Internet Explorer 11 fún àwọn Akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ nínú IT àti àwọn Olùmúgbèrú fún Windows 7
Yára síi. Ààbò síwájú síi. Internet Explorer 11 ni ẹ̀rọ aṣàwákiri tí a dámọ̀ràn fún Windows 7.
Pàtàkì! Yíyan èdè kan nísàlẹ̀ yìí yóò ṣàyípadà gbogbo àkóónú ojú-ìwé náà sí èdè yẹn.
Ẹ̀yà:
11.0.0.0
Ọjọ́ Àtẹ̀jáde:
6/11/2013
Orúkọ Fáìlì:
IE11-Windows6.1-x86-yo-ng.exe
Ìwọ̀n títóbi Fáìlì:
29.2 MB
Àwọn àkọsílẹ̀ KB:
Yára síi. Ààbò síwájú síi. Internet Explorer 11 ni ẹ̀rọ aṣàwákiri tí a dámọ̀ràn fún Windows 7.Àwọn Ìlànà-iṣẹ́ Ẹ̀rọ tó ní Àtìlẹ́yìn
Windows 7 Service Pack 1
- Kọ̀ǹpútà/ Odó ìṣirò kọ̀ǹpútà Kọ̀ǹpútà pẹ̀lú odó ìṣirò kọ̀ǹpútà 233MHz tàbí ju bẹ́ẹ̀ lọ (Odó ìṣirò kọ̀ǹpútà pẹ́ntíọ̀mù ni a gbàníyànjú)
- Àpò ìrántí: 512MB
- Àyè Àwo àká-ọ̀rọ̀ Gbagidi:70MB
- Àfihàn: VGA gidi (800 x 600) tàbí aṣàfihàn ìtànsán-gíga pẹ̀lú àwọn àwọ̀ 256.
- Àwọn ẹ̀yà ara: Módẹ̀mù tàbí Ìsopọ̀ ayélujára; Atọ́ka Microsoft, Microsoft IntelliMouse, tàbí ẹ̀rọ ìtọ́ka tó dọ́gba.
- Tẹ Ìgbàsílẹ̀ bọ́tìnnì lórí ojú-ìwé yìí láti bẹ̀rẹ̀ ìgbàsílẹ̀ náà.
- Ṣe ọ̀kan nínú ìwọ̀nyí:
- Láti bẹ̀rẹ̀ àgbékalẹ̀ lójú ẹsẹ̀, tẹ Ṣí tàbí Mú ètò yìí ṣiṣẹ́ láti ipò rẹ ìsinsìnyí
- Láti da ìgbàsílẹ̀ kọ sórí kọ̀ǹpútà rẹ fún àgbékalẹ̀ lọ́jọ́ iwájú, tẹ Ṣàfipamọ́ tàbí Ṣàfipamọ́ ètò yìí sí dísíkì