Trace Id is missing

Ìkópọ̀ Èròjà Èdè Microsoft® Office – Yòrùbá

Ìkópọ̀ Èròjà Èdè Microsoft Office - Yòrùbá fikún àfihàn, ìrànwọ́, tàbí àwọn irinṣẹ́ àrídájú tó dá lórí èdè tí o fẹ́ ṣàgbékalẹ̀.

Pàtàkì! Yíyan èdè kan nísàlẹ̀ yìí yóò ṣàyípadà gbogbo àkóónú ojú-ìwé náà sí èdè yẹn.

Ìgbé-fáìlì-wálẹ̀
  • Ẹ̀yà:

    2016/2019

    Ọjọ́ Àtẹ̀jáde:

    16/3/2016

    Orúkọ Fáìlì:

    Office2016_LAP_Readme_yo-ng.docx

    Ìwọ̀n títóbi Fáìlì:

    22.5 KB

    Ìkópọ̀ Èròjà Èdè Microsoft Office - Yòrùbá fikún àfihàn, ìrànwọ́, tàbí àwọn irinṣẹ́ àrídájú tó dá lórí èdè tí o fẹ́ ṣàgbékalẹ̀.
    Lẹ́yín tí o bá ti ṣàgbékalẹ̀, Ìkópọ̀ Èròjà Èdè Microsoft -Yòrùbá àwọn agbára àti ẹ̀yán tó bamu wà nílẹ̀ láti àtòjọ ètò Office àti àtòjọ ètò èdè Microsoft Office to fẹ́ jù.
  • Àwọn Ìlànà-iṣẹ́ Ẹ̀rọ tó ní Àtìlẹ́yìn

    Windows 10, Windows 7, Windows 8

      Fún détà tuntun lórí ìnílò Ẹ̀rọ wo ìtọ́kasíÌnílò Ẹ̀rọ fún Office
      Microsoft Windows 8 - 32 tàbí 64 bit OS
      Microsoft Windows 10 - 32 tàbí 64 bit OS. (Fún àwọn olùlò ìrajà ìlò ẹ̀kan Office 2019 Windows 10 nìkan ní OS tó ba ṣiṣẹ̀)
      Àkíyèsí:Jọ̀wọ́ rídájú láti ṣàgbékalẹ̀ Àkójọpọ̀ Ìpèsè tuntun fún Ìlànà Ètò Ìmú-ṣiṣẹ́ e láti ṣàrídájú ìwúlò àtìlẹyìn kíkún fún èdè rẹ.

    Ẹ̀yà àìrídìmúÈyìkèyí ẹ̀yà Office 2016 (tàbí tuntun) ìkópọ̀ tàbí èyí tó dádúró tó ní Microsoft Excel, Microsoft Lync, Microsoft OneNote, Microsoft Outlook, Microsoft PowerPoint tàbí Microsoft Word ma ṣàtìlẹyìn fún Ìkópọ̀ Èròjà èdè Microsoft Office 2016 (tàbí tuntun) - Yòrùbá.
    Kọ̀mpútà àti Odó ìṣirò kọ́mpútàOdó ìṣirò kọ́mpútà1.6 GHz pẹ̀lú SSE2 ṣàtìlẹyìn tàbí gíga; 4GB RAM; 2 GB RAM (32-bit) tàbí gíga

    Àyè dísìkìLáfikún sí àye hard disc tí o lò nípasẹ̀ àtòjọ ètò Office tó ti ṣàgbékalẹ̀,
  • 4GB nínu àyè hard disc tó wà nílẹ̀.

  • Gbogbo ìnílò ẹ̀rọ tókù jẹ́ ìkanáà gẹ́gẹ́ bí àwọn àtòjọ ètò Office tí ò ń lò pẹ̀lú Ìkópọ̀ Èròjà Èdè Microsoft Office - Yòrùbá.


  • Àkópọ̀ Atókù Èdè WindowsA gbàọ́níyànjú láti ṣàgbékalẹ̀ Àkópọ̀ Atókù Èdè Windows tuntun fún àtìlẹyìn èdè kíkún fún Ìlànà Ètò Ìmúṣiṣẹ́ àti àtòjọ ètò Ẹ̀yà àìrídìmú.

    Ìfihàn àwọ̀ agbàwòrántàn àti ààtò DPIỌ̀pọ̀lọpọ̀ fọ́ntì ní a ti ṣẹ̀dá láti kàá ní kíkún ní agbàwòrántán 1366 x 768. Tó bá ní ìsòro kíka fọ́ntì èdè rẹ jọ̀wọ́ ṣàfikún ààtò àfihàn rẹ sí agbàwòrántán tàbí gíga tó bá pọndandan. Jọ̀wọ́ ṣe àkíyèsí: a gbàọ́níyànjú láti lo àtòjọ ètò Office ní ààtò àkùnàyàn DPI Windows - 96 DPI. Lílo ààto DPI 120 lè fa ìrírí olùlò Office tí kò dára nínu àwọn àtòjọ Office kaǹkan nípa fífikún ìwọ̀n ìsọ̀rọ̀gbèsì.

    Ẹ̀yan Èdè àti AgbègbèLáfikún a gbàọ́níyánju pé gbogboẸ̀yan Èdè àti AgbègbènínuPánẹ́ẹ̀lì Ìdaríní a ṣètò sí Ìkópọ̀ Èròjà Èdè Microsoft Office - Yòrùbá.

  • Láti ṣàgbékalẹ̀ Ìkópọ̀ Èròjà Èdè Microsoft Office:
    1. Gba ẹ̀dà fáìlì Ìkópọ̀ Èròjà ÈdèṢàgbékalẹ̀ fáìlì nípasẹ̀ ìtọ́kasí yìíGba ẹ̀dá fáìlì Aṣàgbékalẹ̀ Ìkópọ́ Èròjà Èdè
    2. Nígbàtí o bá Parí Gbígba ẹ̀dá fáílí sílẹ̀ Yan Múṣiṣẹ̀.
    3. Tẹ̀lẹ́ ìtọ́sọ́nà lórí àfihàn náà láti parí ìṣàgbékalẹ̀.

    Sípòpadà sí àtókùn olùlò sí Ìkópọ́ Èròjà Èdè
    Lẹ́yìn tí o bá ti ṣàgbékalẹ̀ Ìkópọ́ Èròjà Èdè, o lè ṣípòpadà èdè àtókùn olùlò sí Yòrùbá láti inú àtòjọ ètò Office tàbí láti àtòjọ ètò Èdè tó fẹ́ jù Microsoft Office.

    Láti ṣípopadà atókùn olùlò èdè láti Èdè tó fẹ́ jù:

    1. Ṣàfilọ́lẹ̀Edè tó fẹ́ jù Office
    2. NínuYan àtòkọ Àwọn Ìṣàtúnṣe Èdè, yan ìṣàtúnṣe èdè kí o sì tẹṢètò gẹ́gẹ́ bí bọ́tìnnì Àkùnàyàn.
    3. NínuYan àtòkó Ṣàfihàn àti àwọn èdè Ìrànwọ́, yanṢàfihàn Èdè rẹ kí o sì tẹṢètò gẹ́gẹ́ bí bọ́tìnnì Àkùnàyàn.
    4. TẹBẸ̀Ẹ́NI.

    Láti ṣípopadà atókùn olùlò èdè láti ini àtòjọ petpo Office:

    1. Lọ síFáìlì, Ẹ̀yán, kí o sì yanÈdè.
    2. NínuYan àtòkọ Àwọn Ìṣàtúnṣe Èdè, yan ìṣàtúnṣe èdè kí o sì tẹṢètò gẹ́gẹ́ bí bọ́tìnnì Àkùnàyàn.
    3. NínuYan àtòkó Ṣàfihàn àti àwọn èdè Ìrànwọ́, yanṢàfihàn Èdè rẹ kí o sì tẹṢètò gẹ́gẹ́ bí bọ́tìnnì Àkùnàyàn.
    4. TẹBẸ̀Ẹ́NI.

    Ààtò èdè tí o yàn ma bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣiṣẹ́ nígbà míràn tí o bá bẹ̀rẹ̀ àtòjọ ètò Office.

    Yí sípẹ́lì èdè padà
    Ìkópọ̀ Èròjà Èdè Microsoft Office - Yòrùbá lè pẹ̀lú àwọn àrídájú irinṣẹ́ nínu èdè rẹ. Èyí ní bí o ṣe lè yí sípẹ́lì èdè padà fún ẹ̀yán ẹyọ ọ̀rọ̀:

    Excel:Excel lo ìṣàtúnṣe àkókọ́ ààtò èdè Microsoft Office láti mọ èdè sípẹ́lì àkùnàyàn. Láti yí èyí padà, yanFáìlìkí o tẹẸ̀yán.TẹẹyánÌṣàrídájú kí o sì mu ìkan lára àwọn èdè tó wá nílẹ̀ láti inúÈdè Atúmọ̀ èdèÀtòkọ.

    Outlook, PowerPoint, Word àti OneNote:Yan ẹyọ ọ̀rọ̀ tí o wù ọ́ láti ṣàyẹ̀wò sípẹ́lì, tẹṢàtúnyẹ̀wò, tẹbọ́tìnnì Èdè, kí o tẹẹ̀yán Ṣètò Ìṣàrídájú Èdè. Yan èdè tó fẹ́rán jù láti àpótí àtòkọ kí o wá tẹBẸ̀Ẹ́NI.