Trace Id is missing

Èdè ìtanilólobó Ìbòjú fún Microsoft Office

Lo ìtumọ̀-èdè inú Ìtanilólobó Ìbòjú lati fi ọ̀rọ̀ inú awọn ohun ti a ṣe àfihàn rẹ̀ hàn - gẹgẹ bíi awọn àkójọ àṣàyàn ati awọn àpótí ìbáraẹnisọ̀rọ̀ - ní èdè miiran.

Pàtàkì! Yíyan èdè kan nísàlẹ̀ yìí yóò ṣàyípadà gbogbo àkóónú ojú-ìwé náà sí èdè yẹn.

  • Ẹ̀yà:

    1.0

    Ọjọ́ Àtẹ̀jáde:

    27/2/2013

    Orúkọ Fáìlì:

    screentiplanguage_yo-ng_32bit.exe

    screentiplanguage_yo-ng_64bit.exe

    Ìwọ̀n títóbi Fáìlì:

    1.5 MB

    1.5 MB

    Yí Èdè ìtanilólobó Ìbòjú padà lati fi ìtumọ̀-èdè awọn àfihàn hàn - gẹgẹ bíi awọn bọ́tìnì, awọn àkójọ àṣàyàn ati awọn àpótí ìbáraẹnisọ̀rọ̀ - ní èdè miiran, kí o si ran awọn olùmúlò lọ́wọ́ lati lọ kaakiri awọn ohun èlò Microsoft Office tí a fi sórí ẹ̀rọ ní èdè tí kò yé wọn.


    Awọn àpẹẹrẹ ọ̀nà ìmúlò ni:
    • Olùrànlọ́wọ́ fún awọn elédè-méjì ati awọn elédè-púpọ̀
    • Awọn Oniṣẹ-ẹ̀rọ olùrànnilọ́wọ́ le ṣe àfikún àtìlẹ́yìn fún awọn èdè tí kò yé wọn.
    • Awọn olùmúlò ti nlo Office fún ìgbà díẹ̀̀ ní èdè ti ilu òkèèrè tabi fún àkókò ti kò gùn púpọ̀ (Awọn olùmúlò ti nlọ kaakiri)
    • Lílò èdè PC ti a ṣe àjọpín rẹ̀
  • Àwọn Ìlànà-iṣẹ́ Ẹ̀rọ tó ní Àtìlẹ́yìn

    Windows 7, Windows 8 Release Preview

    • Awọn ohun èlò Microsoft Office ti o ni Àtìlẹ́yìn
        Microsoft Office Word 2013, Microsoft Office Excel 2013, Microsoft Office Outlook 2013, Microsoft Office PowerPoint 2013, Microsoft Office OneNote 2013, Microsoft Office Visio 2013, Microsoft Office Publisher 2013
    • O nilo software:
        Awọn èdè ilu Ila oorun Eṣia ati awọn èdè ti Kíkọsílẹ̀ wọn Ṣoro le nilo pe ki a fi awọn faili àtìlẹ́yìn wọn sórí ẹ̀rọ. Eyi ṣe e ṣe lati inu Panẹli Ìṣàkóso ni 'Awọn àṣàyàn Èdè ati Agbègbè'.
  • Lati fi àgbéwálẹ̀ naa sórí ẹ̀rọ:
    1. Tẹ bọtini Gbéewálẹ̀ ni ojú-ìwé yi lati bẹ̀rẹ̀.
    2. Ṣe ọ̀kan ninu eyi:
      • Lati bẹ̀rẹ̀ fifi sórí ẹ̀rọ naa lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, tẹ Múu ṣiṣẹ.
      • Lati fi àgbéwálẹ̀ naa pamọ́ sínú ẹ̀rọ kọmputa rẹ fún fifi sórí ẹ̀rọ nigba miiran, tẹ Fipamọ́.
      • Lati fagilé fifi sórí ẹ̀rọ naa, tẹ Fagilé e.

    Lati pa Èdè ìtanilólobó Ìbòjú naa, tabi lati yíi padà:
    1. Tẹ bọtini Office File, yan Awọn àṣàyàn, yan Èdè, ki o si ṣètò Èdè ìtanilólobó Ìbòjú sí 'Bá Èdè Àfihàn dọ́gba'.

    Lati mú àgbéwálẹ̀ naa kúrò:
    1. Lati àkójọ àṣàyàn Bẹ̀rẹ̀, lọ si Panẹli Ìṣàkóso.
    2. Tẹ Fi Ètò kún-un/Yọ Ètò kúrò lẹ́ẹ̀mẹjì.
    3. Ninu àkójọ awọn ètò ti a ṣẹṣẹ fi sórí ẹ̀rọ, yan Èdè ìtanilólobó Ìbòjú fún Microsoft Office, ki o si tẹ Múu kúrò tabi Fi kún-un/Yọ ọ́ kúrò. Bí àpótí ìbáraẹnisọ̀rọ̀ kan bá hàn, tẹ̀lé ìtọ́nisọ́nà naa lati yọ ètò naa kúrò.
    4. Tẹ Bẹ́ẹ̀ni tabi Ó dára lati jẹri síi wípé o fẹ́ yọ ètò naa kúrò.