Trace Id is missing

Internet Explorer 11 fún àwọn Akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ nínú IT àti àwọn Olùmúgbèrú fún Windows 7 Ẹ̀yà bíìtì-64 àti Windows Server 2008 R2 Ẹ̀yà bíìtì-64

Yára síi. Ààbò síwájú síi. Internet Explorer 11 ni ẹ̀rọ aṣàwákiri tí a dámọ̀ràn fún Windows 7.

Pàtàkì! Yíyan èdè kan nísàlẹ̀ yìí yóò ṣàyípadà gbogbo àkóónú ojú-ìwé náà sí èdè yẹn.

Ìgbé-fáìlì-wálẹ̀
  • Ẹ̀yà:

    11.0.0.0

    Ọjọ́ Àtẹ̀jáde:

    6/11/2013

    Orúkọ Fáìlì:

    IE11-Windows6.1-x64-yo-ng.exe

    Ìwọ̀n títóbi Fáìlì:

    54.8 MB

    Àwọn àkọsílẹ̀ KB:

    KB2841134

    Yára síi. Ààbò síwájú síi. Internet Explorer 11 ni ẹ̀rọ aṣàwákiri tí a dámọ̀ràn fún Windows 7.
  • Àwọn Ìlànà-iṣẹ́ Ẹ̀rọ tó ní Àtìlẹ́yìn

    Windows 7 Service Pack 1, Windows Server 2008 R2 SP1

    • Kọ̀ǹpútà/ Odó ìṣirò kọ̀ǹpútà Kọ̀ǹpútà pẹ̀lú odó ìṣirò kọ̀ǹpútà 233MHz tàbí ju bẹ́ẹ̀ lọ (Odó ìṣirò kọ̀ǹpútà pẹ́ntíọ̀mù ni a gbàníyànjú)
    • Àpò ìrántí: 512MB
    • Àyè Àwo àká-ọ̀rọ̀ Gbagidi:70MB
    • Àfihàn: VGA gidi (800 x 600) tàbí aṣàfihàn ìtànsán-gíga pẹ̀lú àwọn àwọ̀ 256.
    • Àwọn ẹ̀yà ara: Módẹ̀mù tàbí Ìsopọ̀ ayélujára; Atọ́ka Microsoft, Microsoft IntelliMouse, tàbí ẹ̀rọ ìtọ́ka tó dọ́gba.
    1. Tẹ Ìgbàsílẹ̀ bọ́tìnnì lórí ojú-ìwé yìí láti bẹ̀rẹ̀ ìgbàsílẹ̀ náà.
    2. Ṣe ọ̀kan nínú ìwọ̀nyí:
      • Láti bẹ̀rẹ̀ àgbékalẹ̀ lójú ẹsẹ̀, tẹ Ṣí tàbí Mú ètò yìí ṣiṣẹ́ láti ipò rẹ ìsinsìnyí
      • Láti da ìgbàsílẹ̀ kọ sórí kọ̀ǹpútà rẹ fún àgbékalẹ̀ lọ́jọ́ iwájú, tẹ Ṣàfipamọ́ tàbí Ṣàfipamọ́ ètò yìí sí dísíkì